Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 82:6-8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

6. “Mo wí pé, ‘Ẹyin ní “Ọlọ́run òrìṣà”;ẹ̀yin ní gbogbo ọmọ ọ̀gá ògo jùlọ.’

7. Ṣùgbọ́n ẹ̀yin o kú bí ènìyàn lásán;ẹ̀yin ó ṣubú bí ọ̀kan nínú ọmọ aládé.”

8. Dìde Ọlọ́run ṣe ìdájọ́ ayé,nítorí gbogbo orílẹ̀ èdè ni ìní Rẹ.

Ka pipe ipin Sáàmù 82