Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 79:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ràn wá lọ́wọ́, Ọlọ́run Olùgbàlà wa,fún ògo orukọ Rẹ;gbà wá kí o sì dárí ẹ̀ṣẹ̀ wa jìnnítorí orúkọ Rẹ.

Ka pipe ipin Sáàmù 79

Wo Sáàmù 79:9 ni o tọ