Àwọn orílẹ̀ èdè yóò sì máa wí pé,“Níbo ni Ọlọ́run wọn wà?”ní ojú wa.Kí a mọ̀ láàrin àwọn orílẹ̀ èdèkí ó sì gbẹ̀san àwọn ẹ̀jẹ̀ ìránṣẹ́ Rẹ̀ tí a tú jáde.