Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 79:11-13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

11. Jẹ́ kí ìmí ẹ̀dùn oǹdè náà wá ṣíwájú Rẹ,gẹ́gẹ́ bí títóbi agbára Rẹìwọ ṣe ìtọ́jú àwọn ti a dá lẹ́bí ikú.

12. San án padà sí àyà àwọn aládùúgbò wa nígbà méjenípa ẹ́gàn tí wọn tí gàn ọ́ Olúwa.

13. Nígbà náà àwa ènìyàn Rẹ,àgùntàn pápá Rẹ,yóò fi ọpẹ́ fún ọ títí láé;láti ìran dé ìranni àwa ó fi ìyìn Rẹ hàn.

Ka pipe ipin Sáàmù 79