Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 67:1-4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Kí Ọlọ́run kí ó ṣàánú fún wa kí o sì bùkún fún wakí ó sì jẹ́ kí ojú Rẹ̀ tàn yí wa ká,

2. kí ọ̀nà Rẹ̀ le di mímọ̀ ní ayé,ìgbàlà Rẹ̀ láàrin àwọn orílẹ̀ èdè.

3. Kí àwọn ènìyàn kí ó yìn ọ́, Ọlọ́run;kí gbogbo ènìyàn kí o yìn ọ!

4. Kí orílẹ̀ èdè kí o yọ̀, kí o sì kọrin fún ayọ̀,nítorí ìwọ fi òdodo darí àwọn ènìyànìwọ si jọba àwọn orílẹ̀-èdè ní ayé.

Ka pipe ipin Sáàmù 67