Kí orílẹ̀ èdè kí o yọ̀, kí o sì kọrin fún ayọ̀,nítorí ìwọ fi òdodo darí àwọn ènìyànìwọ si jọba àwọn orílẹ̀-èdè ní ayé.