Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 47:7-9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

7. Nítorí Ọlọ́run ni ọba gbogbo ayéẹ kọrin ìyìn pẹ̀lú Sáàmù!

8. Ọlọ́run jọba lórí gbogbo ayé;Ọlọ́run jókòó lórí ìtẹ́ ìwà mímọ́ Rẹ̀

9. Àwọn aládé ayé kó ara wọn jọgẹ́gẹ́ bí ènìyàn Ọlọ́run Ábúráhámùnítorí asà ayé ti Ọlọ́run niòun ni ó ga jùlọ.

Ka pipe ipin Sáàmù 47