Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 42:9-11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

9. Èmi wí fún Ọlọ́run àpátà mi,“Èéṣe tí ìwọ fi gbàgbé mi?Èéṣe tí èmi o fi máa rìn nínú ìbànújẹ́,nítorí ìnilára ọ̀ta?”

10. Bí ẹni pé idà egungun mi ni ẹ̀gàn tíàwọn ọ̀ta mi ń gàn mí,Bí wọn ti ń béèrè ni gbogbo ọjọ́.“Níbo ni Ọlọ́run Rẹ wà?”

11. Èéṣe tí ìwọ fi ń rẹ̀wẹ̀sì, ìwọ ọkàn mi?Èéṣe tí ara Rẹ kò fi lélẹ̀ nínú mi?Fi ìrètí Rẹ sínú Ọlọ́run,nítorí èmi yóò sì máa yìn ín, Òun niOlùgbàlà mi àti Ọlọ́run mi.

Ka pipe ipin Sáàmù 42