Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 42:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èéṣe tí ìwọ fi ń rẹ̀wẹ̀sì, ìwọ ọkàn mi?Èéṣe tí ara Rẹ kò fi lélẹ̀ nínú mi?Fi ìrètí Rẹ sínú Ọlọ́run,nítorí èmi yóò sì máa yìn ín, Òun niOlùgbàlà mi àti Ọlọ́run mi.

Ka pipe ipin Sáàmù 42

Wo Sáàmù 42:11 ni o tọ