Olùgbàlà mi àtiỌlọ́run mi,ọkàn mi ń rẹ̀wẹ̀sì nínú mi:nítorí náà, èmi ó rántí Rẹláti ilẹ̀ Jọ́dánì wá,láti Hámónì láti òkè Mísárì.