Jẹ́ kí gbogbo àwọn tí ń wá ọkí ó máa yọ̀kí inú wọn sì máa dùn sí ọ;kí gbogbo àwọn tí ó sì fẹ́ ìgbàlà Rẹkí o máa wí nígbà gbogbo pé,“Gbígbéga ni Olúwa!”