Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 40:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí pé àìníye ibini ó yí mi káàkiri,ẹ̀ṣẹ̀ mi sì dì mọ́ mi,títí tí èmi kò fi ríran mọ́;wọ́n pọ̀ ju irun orí mi lọ,àti wí pé àyà mí ti kùnà.

Ka pipe ipin Sáàmù 40

Wo Sáàmù 40:12 ni o tọ