Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 40:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Mo fi pẹ̀lẹ́pẹ̀lẹ́ dúró de Olúwa;ó sì dẹtí sí mi, ó sì gbọ́ ẹkún mi.

2. Ó fà mí yọ gòkèláti inú ihò ìparun,láti inú ẹrẹ̀ pọ̀tọ̀pọ́tọ̀,ó sì fi ẹsẹ̀ mi lé orí àpáta,ó sì jẹ́ kí ìgbesẹ̀ mi wà láìfòyà.

3. Ó fi orin titun sí mi lẹ́nu,àní orin ìyìn sí Ọlọ́run wa.Ọ̀pọ̀ yóò ríi wọn yóò sì bẹ̀rù,wọn yóò sì gbẹ́kẹ̀ lé Olúwa.

Ka pipe ipin Sáàmù 40