Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 37:40 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa yóò ràn wọ́n lọ́wọ́yóò sì gbà wọ́n;yóò gbà wọ́n lọ́wọ́ ènìyàn búburú,yóò sì gbà wọ́n là,nítorí tí wọ́n gbẹ́kẹ̀ lé e.

Ka pipe ipin Sáàmù 37

Wo Sáàmù 37:40 ni o tọ