Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 37:39-40 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

39. Ìgbàlà àwọn adúró ṣinṣinwa láti ọ̀dọ̀ Olúwa:òun ni ààbò wọn ní ìgbà ìpọ́njú

40. Olúwa yóò ràn wọ́n lọ́wọ́yóò sì gbà wọ́n;yóò gbà wọ́n lọ́wọ́ ènìyàn búburú,yóò sì gbà wọ́n là,nítorí tí wọ́n gbẹ́kẹ̀ lé e.

Ka pipe ipin Sáàmù 37