Bí mo tílẹ̀ ń rìnLáàrin àfonífojì òjiji ikú,èmi kì yóò bẹ̀rù ibi kan;nítorí ìwọ wà pẹ̀lú ù mi;ọ̀gọ Rẹ àti ọ̀pá à Rẹwọ́n ń tù mi nínú.