Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 23:1-4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Olúwa ni Olùsọ́ àgùntàn mi, èmi kì yóò ṣe aláìní.

2. Ó mú mi dùbúlẹ̀ síbi pápá oko tútùÓ mú mi lọ síbi omí dídákẹ́ rọ́rọ́;

3. Ó mú ọkàn mi padà bọ̀ sípòÓ mú mi lọ sí ọ̀nà ododonítorí orúkọ Rẹ̀.

4. Bí mo tílẹ̀ ń rìnLáàrin àfonífojì òjiji ikú,èmi kì yóò bẹ̀rù ibi kan;nítorí ìwọ wà pẹ̀lú ù mi;ọ̀gọ Rẹ àti ọ̀pá à Rẹwọ́n ń tù mi nínú.

Ka pipe ipin Sáàmù 23