Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 18:43 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ ti gbà mí lọ́wọ́ ìkọlù àwọn ènìyàn;Ìwọ ti fi mí ṣe olórí àwọn orílẹ́ èdè;àwọn ènìyàn ti èmi kò mọ, yóò sì máa sìn mí.

Ka pipe ipin Sáàmù 18

Wo Sáàmù 18:43 ni o tọ