Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 17:6-9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

6. Èmi ké pè ọ́, Olúwa, nítorí tí iwọ yóò dá mi lóhùndẹ etí Rẹ sími kí o sì gbọ́ àdúrà mi.

7. Fi ìyanu ìfẹ́ ńlá Rẹ hànìwọ tí ó ń pamọ́ ní ọwọ́ ọ̀tún Rẹàwọn tí ó wá ìsádi nínú Rẹ kúrò ní ọwọ́ ọ̀ta wọn.

8. Pa mí mọ́ bí ẹyin ojú Rẹ;fi mí pamọ́ sí abẹ́ òjìji apá Rẹ.

9. Kúrò ní ọwọ́ ọ̀tá tí ó kọjú ìjà sí mi,kúrò ní ọwọ́ àwọn ọ̀ta apani tí ó yí mi ká.

Ka pipe ipin Sáàmù 17