Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 17:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Fi ìyanu ìfẹ́ ńlá Rẹ hànìwọ tí ó ń pamọ́ ní ọwọ́ ọ̀tún Rẹàwọn tí ó wá ìsádi nínú Rẹ kúrò ní ọwọ́ ọ̀ta wọn.

Ka pipe ipin Sáàmù 17

Wo Sáàmù 17:7 ni o tọ