Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 17:2-6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

2. Kí ìdáláre mi wá láti ọ̀dọ̀ Rẹ;kí ojú Rẹ kí ó rí ohun tí ó tọ́.

3. Ìwọ ti dán àyà mi wò, ìwọ sì yẹ̀ mí wò ní òru.Bí ìwọ bá dán mi wò, ìwọ kì yóò rí ohunkóhunèmi ti pinnu pé ẹnu mi kì yóò ṣẹ̀.

4. Bí ó ṣe ti iṣẹ́ ènìyànnípa ọ̀rọ̀ ẹnu Rẹèmi ti pa ara mi mọ́kúrò ní ọ̀nà àwọn ìkà.

5. Ìrìn mí ti jẹ mọ́ ọ̀nà Rẹ;ẹṣẹ̀ mi kì yóò yọ̀.

6. Èmi ké pè ọ́, Olúwa, nítorí tí iwọ yóò dá mi lóhùndẹ etí Rẹ sími kí o sì gbọ́ àdúrà mi.

Ka pipe ipin Sáàmù 17