Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 149:6-9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

6. Kí ìyìn Ọlọ́run kí ó wà ní ẹnu wọnàti idà olójú méjì ní ọ́wọ́ wọn.

7. Láti gba ẹ̀san lára àwọn orílẹ̀ èdè,àti ìjìyà lára àwọn ènìyàn,

8. Láti fi ẹ̀wọ̀n de àwọn ọba wọnàti láti fi ṣẹ́kẹ́ṣẹkẹ̀irin de àwọn ọlọ́lá wọn.

9. Láti ṣe ìdájọ́ tí àkọsílẹ̀ Rẹ̀ sí wọnèyí ni ògo àwọn ènìyàn mímọ́ Rẹ̀.Ẹ fi ìyìn fún Olúwa.

Ka pipe ipin Sáàmù 149