Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 143:9-12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

9. Gbà mí kúrò lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá mi, Olúwa,nítorí èmi fí ara mi pamọ́ sínú Rẹ̀.

10. Kọ́ mi láti ṣe ìfẹ́ Rẹ,nítorí ìwọ ni Ọlọ́run mijẹ́ kí ẹ̀mí Rẹ dídáradarí mi sí ilẹ̀ tí ó tẹ́jú.

11. Nítorí orúkọ Rẹ, Olúwa, sọ ayé mi di ààyè;nínú òdodo Rẹ mú mi jáde nínú wàhálà.

12. Nínú ìfẹ́ Rẹ tí kì í kùnà, ké àwọn ọ̀ta mi kúrò,run gbogbo àwọn ọ̀tá mi,nítorí èmi ni ìránṣẹ́ Rẹ.

Ka pipe ipin Sáàmù 143