Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 143:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jẹ́ kí òwúrọ̀ mú ọ̀rọ̀ ìfẹ́ tí kì í kùnà wá fún mi,nítorí èmi ti gbẹ́kẹ̀ mi lé ọ.Fí ọ̀nà tí èmi i bá rìn hàn mí,nítorí sí ọ ni èmi gbé ọkàn mi sókè.

Ka pipe ipin Sáàmù 143

Wo Sáàmù 143:8 ni o tọ