Mú mi jáde kúrò nínú túbú,kí èmi lè máa yin orúkọ Rẹ.Nígbà náà ni àwọn olódodo yóò péjọ nípa minítorí iwọ yóò fi ọ̀pọ̀lọpọ̀ ba mi ṣe.