Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 142:6-7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

6. Fi etí sí igbe mi, nítorí tí èmiwà nínú àníìrètígbà mí lọ́wọ́ àwọn tí ń lépa mi,nítorí wọ́n lágbára jù mi lọ

7. Mú mi jáde kúrò nínú túbú,kí èmi lè máa yin orúkọ Rẹ.Nígbà náà ni àwọn olódodo yóò péjọ nípa minítorí iwọ yóò fi ọ̀pọ̀lọpọ̀ ba mi ṣe.

Ka pipe ipin Sáàmù 142