Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 136:23-26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

23. Ẹni tí ó rántí wa ní ìwà ìrẹ̀lẹ̀ wa;nítorí tí àánú Rẹ̀ dúró láéláé.

24. Ó sì dá wa ní ìdè lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá wa;nítorí tí àánú Rẹ̀ dúró láéláé.

25. Ẹni tí ó fi oúnjẹ fún àwọn ẹ̀dá gbogbonítorí tí àánú Rẹ̀ dúró láéláé.

26. Ẹ fi ọpẹ́ fún Ọlọ́run ọ̀run;nítorí tí àánú Rẹ̀ dúró láéláé.

Ka pipe ipin Sáàmù 136