Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 136:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ẹ fi ọpẹ́ fún Olúwa nítorí tí ó ṣeun;nítorí tí àánú Rẹ̀ dúró láéláé.

2. Ẹ fi ọpẹ́ fún Ọlọ́run àwọn ọlọ́run:nítorí tí àánú Rẹ̀ dúró láéláé.

Ka pipe ipin Sáàmù 136