Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 131:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítòótọ́ èmi mú ọkàn mi sinmi,mo sì mú-un dákẹ́jẹ́ẹ́,bí ọmọ tí a fi ọwọ ìyá Rẹ̀ gbà ní ẹnu ọmú:ọkàn mí rí gẹ́gẹ́ bí ọmọ tí a já ní ẹnu ọmú.

Ka pipe ipin Sáàmù 131

Wo Sáàmù 131:2 ni o tọ