Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 131:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Olúwa àyà mí kò gbégabẹ́ẹ̀ ní ojú mi kò gbé sókè:bẹ́ẹ̀ ni èmi kò fi ọwọ́ mi lé ọ̀ràn ńlá,tàbí lé ohun tí ó ga jù mí lọ

2. Nítòótọ́ èmi mú ọkàn mi sinmi,mo sì mú-un dákẹ́jẹ́ẹ́,bí ọmọ tí a fi ọwọ ìyá Rẹ̀ gbà ní ẹnu ọmú:ọkàn mí rí gẹ́gẹ́ bí ọmọ tí a já ní ẹnu ọmú.

3. Ísírẹ́lì, ìwọ ní ìrètí ní ti Olúwaláti ìsinsinyí lọ àti láéláé.

Ka pipe ipin Sáàmù 131