Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 122:1-4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Inú mi dùn nígbà tí wọ́n wí fún mi péẸ jẹ́ kí a lọ sílé Olúwa.

2. Ẹsẹ̀ wa yóò dúró ní ẹnu ibodè Rẹ,ìwọ Jérúsálẹ́mù.

3. Jérúsálẹ́mù, ìwọ tí a kọ́ bí ìlútí o fi ara mọ́ra pọ̀ ṣọ̀kan

4. Níbi tí àwọn ẹ̀yà máa ń gòkè lọ,àwọn ẹ̀yà Olúwa,ẹ̀rí fún Ísírẹ́lì, látimáa dúpẹ́ fún orúkọ Olúwa.

Ka pipe ipin Sáàmù 122