Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 120:5-7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

5. Ègbé ni fún mi tí èmi ṣe àtìpó ní Mésékì,nítorí èmi gbé nínú àgọ́ Kédárì!

6. Ó ti pẹ́ tí èmi ti ń gbéláàrin àwọn tí ó kóríra àlàáfíà.

7. Ènìyàn àlàáfíà ni mí;ṣùgbọ́n nígbà tí mo bá sọ̀rọ̀, ogun ni ti wọn.

Ka pipe ipin Sáàmù 120