Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 111:9-10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

9. Ó rán ìràpadà sí àwọn ènìyàn Rẹ̀:ó pàṣẹ májẹ̀mú Rẹ̀ títí láé:mímọ́ àti ọ̀wọ̀ ní orúkọ Rẹ̀.

10. Ìbẹ̀rù Ọlọ́run ni ìpilẹ̀ṣẹ̀ ọgbọ́n:òye dáradára ni yóò máa ṣe òfin Rẹ̀:ìyìn Rẹ̀ dúró láé.

Ka pipe ipin Sáàmù 111