Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 111:8-10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

8. Wọ́n dúró láé àti láé,ní òtítọ́ àti òdodo ní a ṣe wọ́n.

9. Ó rán ìràpadà sí àwọn ènìyàn Rẹ̀:ó pàṣẹ májẹ̀mú Rẹ̀ títí láé:mímọ́ àti ọ̀wọ̀ ní orúkọ Rẹ̀.

10. Ìbẹ̀rù Ọlọ́run ni ìpilẹ̀ṣẹ̀ ọgbọ́n:òye dáradára ni yóò máa ṣe òfin Rẹ̀:ìyìn Rẹ̀ dúró láé.

Ka pipe ipin Sáàmù 111