Yóò ṣe ìdájọ́ láàrin kènfèrí,yóò kún ibùgbé wọn pẹ̀lú òkú ara;yóò fọ́n àwọn olórí ká sí orí ilẹ̀ ayé tí ó gbòòrò.