Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 101:6-8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

6. Ojú mi yóò wà lára àwọn olóòtọ́ lórí ilẹ̀,kí wọn kí ó le máa bá mi gbé;ẹni tí o bá ń rìn ọ̀nà pípéòun ni yóò máa sìn mí.

7. Ẹni tí o bá ń ṣe ẹ̀tàn, kì yóò gbé ilé mi,kò sí ẹni tí ń ṣèké ti yóò dúró ní iwájú mi.

8. Ní ojojúmọ́ ní èmi yóò wá máa pa lẹ́nu mọgbogbo àwọn ènìyàn búburú ilẹ̀ náà;èmi yóò gé àwọn olùṣe búburúkúrò ní ìlú Olúwa.

Ka pipe ipin Sáàmù 101