Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 101:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹnikẹni tí ó bá ń sọ̀rọ̀ ẹnikejì Rẹ̀ ní ìkọ̀kọ̀,oun ní èmi yóò gé kúròẹni tí ó bá gbé ojú Rẹ̀ ga tí ó sì ní ìgbéraga àyà,òun ní èmi kì yóò faradà fún.

Ka pipe ipin Sáàmù 101

Wo Sáàmù 101:5 ni o tọ