Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 100:3-5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

3. Olúwa Ọlọ́run ni ó dá wa,kí ẹyin kí ó mọ̀ pétirẹ̀ ni àwa; Àwa ní ènìyàn Rẹ̀àti àgùntàn pápá Rẹ̀.

4. Ẹ lọ sí ẹnu ọ̀nà Rẹ̀ pẹlú ọpẹ́àti sí àgbàlá Rẹ̀ pẹ̀lú ìyìn;ẹ fi ọpẹ́ àti ìyìn fún orúkọ Rẹ̀.

5. Nítorí tí Olúwa pọ̀ ní ooreìfẹ́ Rẹ̀ sì wà títí láé;àti òtítọ́ Rẹ̀ títí dé gbogbo ayé.

Ka pipe ipin Sáàmù 100