Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 100:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ẹ hó ìhó ayọ̀ sí Olúwa, gbogbo ayé

2. Ẹ fi ayọ̀ sin Olúwa:Ẹ wá ṣíwájú Rẹ̀ pẹ̀lú orin dídùn

Ka pipe ipin Sáàmù 100