Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 1:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ìbùkún ni fún ọkùnrin náà,tí kò rìn ní pa ìmọ̀ràn àwọn ènìyàn búburútàbí ti kò ba àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ rìn pọ̀,tàbí ti kò si bá àwọn ẹlẹ́gàn kẹ́gbẹ́.

2. Ṣùgbọ́n ayọ̀ inú Rẹ̀ wà nínú òfin Olúwaàti nínú òfin Rẹ̀ ni ó ń ṣe àṣàrò ní ọ̀sán àti òru.

3. Ó dàbí igi tí a gbìn sí eti odò tí ń ṣàn,tí ń so èso Rẹ̀ jáde ní àkókò Rẹ̀tí ewé Rẹ̀ kì yóò Rẹ̀.Ohunkóhun tí ó dáwọ́lé,ni yóò máa yọrí sí rere.

Ka pipe ipin Sáàmù 1