Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 1:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìbùkún ni fún ọkùnrin náà,tí kò rìn ní pa ìmọ̀ràn àwọn ènìyàn búburútàbí ti kò ba àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ rìn pọ̀,tàbí ti kò si bá àwọn ẹlẹ́gàn kẹ́gbẹ́.

Ka pipe ipin Sáàmù 1

Wo Sáàmù 1:1 ni o tọ