Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Rúùtù 3:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wòó, Bóásì ọkùnrin nì tí ìwọ bá àwọn ìránṣẹ́-bìnrin rẹ̀ ṣiṣẹ́, tí í ṣe ìbátan wa, yóò wá láti fẹ́ ọkà ní ilẹ̀-ìpakà rẹ̀ ní àṣálẹ́ yìí.

Ka pipe ipin Rúùtù 3

Wo Rúùtù 3:2 ni o tọ