Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Rúùtù 3:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bóásì sì wí fún-un pé, “Kí Olúwa bùkún fún ọ, ọmọbìnrin mi. Ìfẹ́ tí o fi hàn yí ti pọ̀ ju ti àtẹ̀yìnwá lọ, bí ó ti jẹ́ wí pé ìwọ kò lọ láti wá àwọn ọ̀dọ́mọkùnrin bóyá ọlọ́rọ̀ tàbí talákà.

Ka pipe ipin Rúùtù 3

Wo Rúùtù 3:10 ni o tọ