Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Rúùtù 2:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Náómì sì wí fún-un pé, “Kí Olúwa, kí ó bùkún fún ọkùnrin náà. Ọlọ́run kò dáwọ́ oore àti àánú ṣíṣe sí àwọn alààyè àti òkú dúró.” Náómì sì sọ ṣíwájú sí i wí pé, “Ìbátan tí ó súnmọ́ wa pẹ́kípẹ́kí ni ọkùnrin náà ń ṣe, ó sì jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn tí ó ní ẹ̀tó láti ra ohun-ìní ìdílé padà.”

Ka pipe ipin Rúùtù 2

Wo Rúùtù 2:20 ni o tọ