Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Rúùtù 2:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìyá ọkọ rẹ̀ sì bi í léèrè wí pé, “Níbo ni ìwọ ti ṣa ọkà lónìí? Àti wí pé oko ta ni ìwọ gbé ṣiṣẹ́? Alábùkún fún ni ọkùnrin náà tí ó bojú wò ọ.”Rúùtù sì sọ ọ̀dọ̀ ẹni tí ó ti ṣiṣẹ́ fún ìyá ọkọ rẹ̀ pé, “Ní oko ọkùnrin kan tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Bóásì ni òun ti ṣiṣẹ́ lónìí.”

Ka pipe ipin Rúùtù 2

Wo Rúùtù 2:19 ni o tọ