Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Rúùtù 1:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Orúkọ ọkùnrin náà ń jẹ́ Elimélékì, orúkọ ìyàwó rẹ̀ ni Náómì, orúkọ àwọn ọmọ rẹ̀ méjèèjì sì ni Málónì àti Kílíónì àwọn ará Éfúrétà, ti Bẹ́tílẹ́hẹ́mù ti Júdà. Wọ́n sì lọ sí ilẹ̀ Móábù, wọ́n ń gbé níbẹ̀.

Ka pipe ipin Rúùtù 1

Wo Rúùtù 1:2 ni o tọ