Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Òwe 29:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Aláìgbọ́n ènìyàn fi gbogbo ẹ̀nú rẹ̀ bínúṣùgbọ́n ọlọgbọ́n ènìyàn a máa kó ìbínú rẹ̀ ní ìjánu.

Ka pipe ipin Òwe 29

Wo Òwe 29:11 ni o tọ