Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Òwe 27:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí a tilẹ̀ gún aláìgbọ́n nínú odó,fi ọmọ odó gún-un bí èlùbọ́ìwọ kì yóò le è yọ ìwà òmùgọ̀ rẹ̀ kúrò ní inú rẹ̀.

Ka pipe ipin Òwe 27

Wo Òwe 27:22 ni o tọ