Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Òwe 24:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Má ṣe wí pé, “Mà á ṣe é fún un gẹ́gẹ́ bí ó ti ṣe fún mi;Èmi yóò san ohun tí ó ṣe fún mi padà fún un.”

Ka pipe ipin Òwe 24

Wo Òwe 24:29 ni o tọ