Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Òwe 24:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí bí olódodo ènìyàn bá tilẹ̀ ṣubú ní ìgbàméje, yóò tún padà dìde ṣáá ni,ṣùgbọ́n ìdàámú yóò fa ènìyàn búburú lulẹ̀.

Ka pipe ipin Òwe 24

Wo Òwe 24:16 ni o tọ